Eniola Ogungbe is a spirit filled Gospel music minister,recording artiste, a lead vocalist, composer and praise lover, whom God has been using to bless this generation through her ministrations.
'Oba Ni O' is an inspirational song exalting God and precisely giving reference to his names, kingship and what he is capable of doing at the mention of those names.
Written and composed by Eniola Ogungbe.
Produced by Emmanuel Aboluwade.
Lyrics
Oba Ni OChorusOba ni o laye lorun kos'oba b'ireatobatele k'oto j'oba Olorun agbayeYawhe, most high l'oruko re ayin oEmmanuel, wonder igbala waEma ma seVerse 1Oba t'oti wa k'aye to waIpinle ohun gbogboAlabo, olufe, ol'oruko egbaagbejen o p'oruko rek'aye le mo b'oti tobi tokari-ola, kari-ile odansaki re o babaChorusOba ni o laye lorun kos'oba b'ireatobatele k'oto j'oba Olorun agbayeYawhe, most high l'oruko re ayin oEmmanuel, wonder igbala waEma ma seVerse 2Oro ti ngbe oro miIjinle t'oju imule loAtobiju, ajunilo, adakeja, ajamajebiOruko re le ni'gbamo wo yika aye, o o l'afiweti m'ba ni nka'ruko reile asu, ile amoChorusOba ni o laye lorun kos'oba b'ireatobatele k'oto j'oba Olorun agbayeYawhe, most high l'oruko re ayin oEmmanuel, wonder igbala waema ma seBridgeOmimi mi'le mi'gi oko l'olruko to n jeOgbon t'oju ogbon loOlogbon to mu omi wo'nu agbonAdanimadale eniIkoko ti nbo gbogbo agbayeAfunni ma si'regun oOba oba oba niCall: E bami pe oResponse: Oba niCall: E pee oResponse: Oba niCall: Oni'budo ogoResponse: Oba niCall: Akikitan, ayinyintan o eResponse: Oba niCall: Oni majemu lae laeResponse: Oba niCall: Kakaki orunResponse: Oba niCall: Aran ma pada tu mo, atu ma pada ranEtc...
0 Comments
Your comment goes a long way in helping our team...
Please drop your comment